Awon aworan nibi ayeye igbeyawo olori-oko Banky W ati iyawo re Adesua. #BAAD2017

1

Ayeye igbeyawo laarin Banky W ati arabirin Adesua Etomi waye lana ni ipinle Eko, opolopo awon gbajugbaja osere, olorin ati awon eyan jankan-jankan lo peju sibe. Adura wa ni wipe ife won o ma gboro si. Amin.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.