1.1 C
London
Tuesday, January 22, 2019

Edakun, ema se fun awon olopa ni oti mu. Oga Olopa Edgal Imohimi...

Oga olopa Edgal Imohimi leyin akiyesi to se nipa iwa-kiwa ti awon agbofinro to ba mu oti amupara ma n wu, o so wipe lati oni lo, enikeni o gbodo fun olopa kankan ni...

Ogbeni Omoyele Sowore lo se abewo si Alafin Oyo, Emir Kano ati awon ori...

Ogbeni Omoyele Sowore, ikan ninu awon oludije fun ipo Aare orilede Nigeria ninu idibo ton bo lona ni odun 2019, loni lo se atejade kan lati ki awon omo orilede Nigeria ku ifarada ati...

Ajo INEC ti yan Oludije labe egbe oloselu APC Gboyega Oyetola gege bi eni...

Oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe egbe oloselu APC ti gbe igba oroko ninu eto idibo to waye ni ipinle na loni. Leyin gbogbo atotonu ati igbiyanju egbe oloselu PDP lati fakoyo ninu eto...

Ajo ASUU ti gun le iyanselodi (strike).

Gege bi atejade ti Aare ajo egbe awon oluko ile iwe giga ASUU ogbeni Biodun Ogunyemi se loni ojo kerinla osu kejo, o so wipe awon ti gun le iyanse lodi latari ai mu...

EBUKA ALAGBADA INA.

  Nibi ayeye igbeyawo Banky W ati Adesuwa Etomi, agbada gbajugbaja osere ati soro-soro EBUKA tayo laarin awon akegbe re. Egan ni e, eni keni to ba ri agbada arakunrin na ti ko ba beri,...

Alakoba lasan lasan ni Kbrule, ohun lo je ki won le mi kuro ninu...

Ninu afihan ati atejade kan ti arabirin Koko, ikan ninu awon oludije BBN ti won ti le lo ile se, o so wipe ogbeni Kbrule ti won so papo mo ohun lo je ki...

Awon agba oloselu lati orisirisi egbe ti korajopo lati koju egbe oloselu APC ninu...

Ipalemo ati akitiyan awon oloselu lati orisirisi egbe oloselu to wa ni orilede Nigeria, lati gba ipo Aare orilede lowo egbe oloselu APC ti bere. Eyi waye latari ipade to waye laarin awon agba-agba...

Dokita kan gba gbajugbaja olorin Phyno ni imoran lati fi ose Soda fo eyin...

Dokita to mo nipa eyin (dentist) kan, dokita Nebeokike Sunday ti se atejade kan lori ero ayelujara facebook lati fi gba odomode olorin Phyno ni imoran lati ma fi ose soda fo eyin re....

Ija dopin, ogun si tan laarin Davido ati Wizkid.

Ija olojo pipe laarin gbajugbaja odomode olorin Wizkid ati akegbe re Davido lana ti pari ni bi ipade orin ti Wizkid gbe kale to waye ni ile itura Eko Hotel ni ipinle Eko.  Iyalenu...

Olori la’fin Cambridge, Kate Middleton ti bi omo kunrin lanti lanti

Olori Kate Middleton ati olowo ori re ti bi omo kunrin lanti-lanti loni. Awon akede afin Kensington Palace lo se atejade na laro kutu-kutu oni. Nkan bi agogo mokanla aro oni ni omo tuntun...