4.2 C
London
Sunday, March 24, 2019

Awon eyan merinla ti so emi won nu ninu ikolu to waye ni ipinle...

Awon Fulani daran-daran ni ana ojo keji osu kesan se ikolu tuntun ni agbegbe Jos South ati ijoba ipinle Bassa ni ipinle Plateau. Awon eyan merinla lo so emi won nu ninu ikolu na. Ikolu...

Ijoba apapo ti pinu lati so ile Fela Anikulapo Kuti ni ipinle Ogun di...

Gege bi atejade ti ijoba apapo se ti Ogbeni Lai Mohamed si so pelu ajosepo Gomina ipinle Ogun, won se afihan wipe ile ti ologbe Fela Anikulapo Kuti gbe dagba ni ipinle Ogun ni...

Don Jazzy, Omojuwa, Tonto Dikeh, Davido ati opolopo awon eyan ba Dbanj kedun lori...

Ibanuje nla lo je nigba ti iroyin iku omo gbajugbaja odomode olorin Dbanj Daniel The Third jade. Omo na ni iwadi fi ye wa wipe o sesi bo sinu omi, ti enikeni o si...

Gomina ipinle Imo Rochas Okorocha fi Aare orilede South Africa Jacob Zuma je oye...

  Aare orilede South Africa Jacob Zuma ti je oye Ochiagha Imo ni ipinle Imo ni ana. Eze Imo, HRH Samuel Ohiri Owerri, ti ipinle Imo lo fi Aare na je oye na, to si...

Ogbeni Fela Durotoye ti gba iwe ase lati egbe oloselu ANN lati tesiwaju ninu...

Oludije fun ipo Aare, Ogbeni Fela Durotoye ti gba iwe ase lati egbe oloselu ANN lati tesiwaju ninu ipinu re lati dije fun ipo Aare ni odun 2019. Eyi ti fi ipinu Ogbeni Durotoye...

#2017MTVEMAs. Atejade gbogbo awon to pegede nibi ayeye na.

Ayeye MTV European Music Awards to waye ni ale oni, ojo aiku ojo kejila osu kokanla ni ilu london lo ri opolopo awon olorin agbaye, ti won si gbiyanju lati ye won si fun...

O ma se o! Ikan ninu awon omobirin gbajugbaja olorin Fuji, KWAM1 ti ku.

Arabirin Wasilat Olaronke Marshall, omobirin omo odun merinlelogbon (34years), omo gbajugbaja olorin KWAM1 ti ku ni orilede Canada. Awon molebi ati ore arabirin na so wipe o ku leyin aisan ranpe kan. Adura wa ni...

O ma se o! ogbeni Jide Tinubu, akobi oga agba egbe oloselu APC...

  Ibanuje nla lo je fun oga agba egbe oloselu APC, Asiwaju Bola Tinubu nigba ti iroyin iku akobi re ni okunrin ogbeni Jide Tinubu to leti. Ologbe na lo so emi re nu ni...

Awon omo egbe agbaboolu Super Eagles na Indomitable Lions ti orilede Cameroon ni omi...

Awon omo egbe agbaboolu Super Eagles loni, koju awon akegbe won lati orilede Cameroon ni papa idaraya Godswill Akpabio International Stadium, ni ilu Uyo, won si gbomi ewuro si won loju nigba ti won...

BA TI FE KO RI, BE NA LO RI EMI LA O NI YO...

Gbajugbaja oserebirin Funke Akindele, eni ti gbogbo eyan mon si Jenifa ti loyun. O se afihan ikun re to se rumu-rumu nibi ayeye ipate Glo-lafta Fest to waye ni osan oni ni agbegbe Festac...