Floyed Mayweather fi Ajeku iya je ogbeni Conor McGregor ninu idije to waye laarin awon mejeji.

0

Idije ese kiku to waye laarin ameseku bi ojo Floyed Mayweather ati Conor McGregor ni oru oni ni ogbeni FloyedMayweather eni ki ko ti padanu idije kankan ri ti fi ajeku iya je akegbe re.

Ipele kewa ni ogbeni Mayweather ti gbegba oroke. Idije na waye ni papa  idaraya T-Mobile Arena ni ilu Las Vegas.

Ija na to je ija elekadorin fun Mayweather ni o ti pinu wipe yo je ija ti ohun yo ja gbeyin gege bi akese. O dupe lowo awon ololufe re, o si ki akegbe re Conor McGregor ku ise .

Awon aworan to jeyo ninu idije na niyi;

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply