Iyawo Aare orilede arabirin Aisha Buhari gba awon obirin ninu egbe oloselu APC lalejo loni.

0

Iyawo Aare orilede arabirin Aisha Buhari loni gba awon obirin to je omo egbe oloselu APC lalejo loni ni ile Aare to wa ni ilu Abuja. Idi ipade yi da le lori ifowosowopo awon omo egbe na, ati igbaradi fun eto idibo ton bo lona. Awon to peju si ibi ipade na ni iyawo igbakeji Aare arabirin Dolapo Osinbajo, Tina Adike, Maryam Mairo Tambuwal, ati awon eyan be be lo.

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply