- 20shares
- 20Facebook
- 0Twitter
- 0Pinterest
- 0LinkedIn
- 0Email
- 0Reddit
Ijoba apapo pelu atileyin IOM (International Organization of Migration) ti ko ipa takuntakun lati ri wipe awon omo Nigeria ton se eru ni orilede Libya toto okòólénígba àti mẹwàá ti pada wale. Ni kete ti won de papako ofurufu Muritala Muhammed ni ipinle Eko ni awon omo egbe ajo NEMA ati NCFRMI (National Commission for Refugees, Migrants and Internally Displaced Persons) tete gba oruko won sile, ti won si bere sini se itoju won pelu Ounje, ile ati owo kekere lati bere aye won pada.
Ijoba apapo orilede Nigeria labe idari Aare Muhamoodu Buhari ti wa pinu lati ko opolopo awon omo orilede yi to si wa ni ilu Libya pada wale
Get more stuff like this
in your inbox
Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.
Thank you for subscribing.
Something went wrong.
Yet to believe this.
How did they get there in d first place?