Senito Dino Melaye fi ijo ati orin kuro ninu egbe oloselu APC bo si egbe oloselu PDP

0

Ninu atejade mohun-maworan kan ti oloselu agba Senito Dino Melaye gbe sori ero ayelujara instagram loni, o fi han wipe ohun ti kuro ninu egbe oloselu APC ohun si ti koja sinu egbe oloselu PDP.

Senito na, fi ijo ati orin da awon ololufe re laraya, o si dupe lowo awon alakoso egbe oloselu PDP fun ife ati anfani ti won fun ohun lati darapo mo won.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply