Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ti farahan gege bi omo oko nigba ti won fi je oye Waziri Ilorin

0

Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ni won ti fi je oye Waziri Ilorin, oye ti baba re Dr. Abubakar Olusola Saraki je ki olojo to de. Ayeye ifinijoye na waye ni Aafin Oba ilorin Emir, Alhaji Ibrahim Sulu Gambari.

Opolopo awon akegbe, ololufe ati awon ore re lo peju sibi ayeye ifinijoye na.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply