Asoju Aare Yemi Osinbajo ti se atejade kan lati se atupale ati atunto ajo SARS

0

Asoju Aare Yemi Osinbajo loni ti se atejade kan lati se atunto patapata ajo Special Anti-Robbery Squad (SARS). Atunto na waye leyin opopopo igbe ati edun okan ti awon omo Nigeria n ke lojojumo latari iwa aibikita ti awon osise na fin sise won ti won sin ni awon omo Nigeria lara.

Atejade na to ti owo agbenuso re Laolu Akande jade lo fi idi oro na mule. Atejade na ni yi ni ede geesi;

“Following persistent complaints and reports on the activities of the Special Anti-Robbery Squad (SARS) that border on allegations of human rights violations, His Excellency, Professor Yemi Osinbajo SAN, Acting-President, Federal Republic of Nigeria, has directed the Inspector General of Police to, with immediate effect, overhaul the management and activities of SARS,” .

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply