#BBNaija: ARO META TI YI OBE DANU; Ogbeni Lolu, Arabirin Khloe ati Anto ti ja danu ninu idije Big Brother Naija

0

O se gbogbo eyan ni kayefi nigba ti awon alakoso ati alamojuto idije Big Brother Naija ja awon oludije meta lekan soso. Ogbeni Lolu, Arabirin Khloe ati Anto ni awon oludije meta ti won ja danu ninu idije na ni ale oni.

Idije na tin sun mo ipari. Awon oludije marun to ku ni Tobi, Alex, Ceec, Nina ati Miracle.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply