#BigBrotherNaija; Arabirin Khloe ati Anto ti pada sinu idijde BBN (Ipadabo awon abija).

0

Leyin gbogbo atotonu ati ipolongo awon ton se akoso idije BBN ni ose to koja wipe awon o da meji ninu awon oludije toti ja lo sile pada, Iyalenu nla lo je fun awon oluworan ati awon ololufe idije na nigba ti won gbo wipe arabirin Khloe ati Anto ni won yan pada lati wa sinu idije na.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply