O ma se o! ogbeni Jide Tinubu, akobi oga agba egbe oloselu APC Asiwaju Bola Tinubu ti ku.

0

 

Ibanuje nla lo je fun oga agba egbe oloselu APC, Asiwaju Bola Tinubu nigba ti iroyin iku akobi re ni okunrin ogbeni Jide Tinubu to leti. Ologbe na lo so emi re nu ni aro kutu-kutu oni. Agbejoro agba ni ologbe na ki olojo to de, to si ti sise pelu awon ile ise bi TSL Limited, Mobil Producing Nigeria, Cargo Maritime, Paris, France, ati Ocean and Oil Services Ltd.

Oloye Henry Ajomale fi idi oro yi mule, o si se atejade kan lati kedun pelu Asiwaju ni ede geesi.

Atejade na ni yi;

Jide Tinubu, son of APC National leader Asiwaju Bola Tinubu, has died

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply