Ogbeni Kayode Fayemi dupe lowo awon ololufe ati alatileyin re leyin igba to gbegba olubori ninu eto idibo Gomina to waye ni ipinle Ekiti

0

Eto idibo Gomina ipinle Ekiti to waye ni ojo kerinla osu keje odun 2018 nibi ti ogbeni Kayode Fayemi ti gbegba olubori. Ogbeni Kayode Fayemi bakana lo dupe gidigidi lowo awon ololufe ati awon alatileyin re fun ifowosopopo ati ife ti won ni si ohun.

O si fi okan won bale wipe lai pe, lai jina, won o bere sini je ere ise owo won pelu ayo ati ifokan bale.

Awon agba oloselu bakana bi oloye Olusegun Obasanjo, Bukola Saraki, Aare Buhari, Lai Muhammed ati bebe lo ti wa ki ku orire.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply