AKU ODUN KERESIMESI O. ODUN A YABO FUN GBOGBO WA.

1

Aku odun keresimesi o, adura wa ni wipe ki odun na san wa si owo, ko san wa si omo, ko si san wa si alafai, aiku baale oro ni oruko Jesu Kristi olugbala wa amin.

KERESIMESI

Keresimesi keresimesi de

Keresimesi de

Abi olugbala kan fun wa

Ni ilu bethleham

Eni ti yio je oba aye ra ye raye

Awa ti ri irawo re ni awo sanmo

A si wa lati mu ebun fun oba ti abi loni.

Kristi alagbawi Eda

Kristi alagbada ina

Kristi aiku ,aisa

Kristi olugbala Eda Eledumare.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

1 COMMENT

Leave a Reply Cancel reply