Awon janduku kan ti ji opa ase ile igbimo asofin orilede Nigeria gbe

1

Ile igbimo asofin daru latari wipe awon janduku kan wo inu gbongbon ipade, ti won si ji opa ase orilede Nigeria gbe salo. Isele na ni awon agbofinro ti fin han wipe o ni ipasepo pelu Senator Ovie Omo-Agege.

Iwadi to peye tin lo lori oro na, ti won si fi okan gbogbo awon omo Nigeria bale wipe awon o gba opa ase na pada.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

1 COMMENT

Leave a Reply Cancel reply