Odaran ati alarun-opolo ni gbogbo awon okunrin to ba’n gbe olosho. Pope Francis lo so be.

0

Nibi ipade kan ti adari awon omo ijo Katoliki mimo Pope Francis se ni orilede Vatican City se pelu awon odo ilu na, o so wipe odaran ati alarun-opolo ni gbogbo awon okunrin to ba ma’n gbe awon olosho ati asewo. O so siwaju si wipe gbogbo awon okunrin yi lon fi iya je awon obirin ti won ba ni ajosepo, o tenu mo wipe ki se ife rara sugbon iwa ika gba ni.

Ni ipari, o so fun gbogbo awon omo Kristeni to ba n se eleyi lati toro idariji ese lowo Olorun Oba.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply