Awon osise ajo EFCC gba posi, igba ati opolopo ogun abenugongo lowo awon odomode marundinlogun ton cha-che. (Yahoo boys).

2

Awon osise ajo Economic and Financial Crimes Commission, EFCC, ti ipinle eko ti mu awon odomode marundinlogun ti won lu jibiti lori ero ayelujara. Oruko awon odaran na ni Adeyemi Tiwatope, 20; Odeyemi Olawale, 20; Nike Afolabi Olaiya, 20; Awe Abimbola Ireti, 23; Yusuf Aliu Oluwafemi, 20; Osidipe Olatunbosun, 24; Tosin Adesanya, 19 and Adeyinka Bello, 17. Others are: Aliu Lukman, 18; Damilola Fatona, 20; Shonubi Adetola, 18; Adewale Babatunde, 17; Afolabi Lekan, 19; Awe Ayodele, 24 and Adeyemi Gbadebo, 19.

Ojo keta osu keji ni owo awon agbofinro ba awon odaran na ni adugbo Shotubo ati Awoluwo ni ilu Shagamu ni ipinle Ogun.

Awon nkan ti won ri gba lowo awon odaran na ni posi, igba, ogun abenugongo, ero ibara eni soro, cardi ipe, oko ayokele, computa ati bebe lo.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

2 COMMENTS

Leave a Reply Cancel reply