Don Jazzy, Omojuwa, Tonto Dikeh, Davido ati opolopo awon eyan ba Dbanj kedun lori iku omo re

0

Ibanuje nla lo je nigba ti iroyin iku omo gbajugbaja odomode olorin Dbanj Daniel The Third jade. Omo na ni iwadi fi ye wa wipe o sesi bo sinu omi, ti enikeni o si mo titi o fi ku.

Awon ore, ati ololufe arakunrin na ti wa se atejade lori ero ayelujara lati ba odomode olorin na ati idile re kedun. Adura wa ni wipe ki Olorun fi opin si iku ewe, ko si petu si okan awon obi omo na. Amin.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply