Ijakadi be si le laarin awon gbajugbaja ibeji olorin Psquare.

0

Leyin gbogbo atotonu lori wipe awon omo iya meji ati ibeji olorin Psquare ti fe tuka, Peter lo se afihan aworan yi lati fi han nibi ti ikeji re ati egbon won Jude ti fe ba ohun ja ijakadi ninu ile ise Agbejoro won, Agbejoro Festus Keyamo.

Ibanuje nla lo je fun gbogbo awon ololufe won nigba ti aworan yi jade. Adura wa ni wipe ki olorun ba won pari ija na ko si fun won ni ogbon lati le mo ona ti won o gba ki alafia le joba. Amin.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply