A dupe o, awon omo egbe agbaboolu Super Eagles ti na iko egbe agbaboolu Zambia ni omi ayo kan si odo.

0

 

Idije boolu alafesegba to waye laarin iko egbe agbaboolu Super Eagles lo pari pelu ayo ati idunu lenu awon ololufe egbe agbaboolu Super eagles nigba ti Victor Iwobi gba omi ayo kan soso si inu awon iko egbe agbaboolu Zambia.

Eyi ti fun won ni anfani lati dije ninu idiji agbaye ton bo lona ni orilede Russia ni odun ton bo. Aku orire o.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply