Gbajugbaja alawada Akpororo ti ko ile awo si fila ni ipinle Eko.

0

Odomode alawada Akpororo ninu atejade kan to se lori ero ayelujara instagram loni lo se afihan ile tuntun awo si fila to sese ko si ipinle Eko. O dupe lowo Olorun, o si kan sara si iyawo re ati omobirin re.  E ku orire o.

Atejade ti arakunrin na se lori ero ayelujara instagram ni yi ni ede geesi;

Except the Lord builds a house. The labourer Labours in vain. Father thank you for this one. I dedicate this to my wife and daughter’.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply