Gomina ipinle Imo, Rochas Okorocha loni se ipade pelu awon oludije Big Brother Naija

0

Gomina ipinle Imo loni gba alejo awon oludije Big Brother Naija ni ile ijoba to wa ni olu ilu ipinle na. Awon merin ti won gba ni alejo ni Miracle, Nina, Teddy A ati arabirin Bam-bam.

Iwadi tun fi ye wa wipe, Gomina Rochas, fun ogbeni Miracle ni ebun ile, ati owo to to Millionu meji, be gege lo fun awon akegbe yoku ni millionu meji-meji.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply