Gomina ipinle Imo Rochas Okorocha ti yan aburo re gege bi comissioner lori eto idunu ati ibagbepo loko-laya.

0

Gomina ipinle Imo loni yan awon comissioner mejidinlogbon si ori oye ni ipinle na. Pambambari re wa ni wipe ikan ninu awon comissioner na je aburo re obirin Arabirin Ogechi Ololo, to si yan lati ma se akoso idunu ati ibagbepo loko-laya ni gbogbo ipinle na. Eku orire o

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply