Ojo ketadinlogun osu karun ni awe Ramadan o bere; Sultan Sokoto lo so be

0

Sultan ilu Sokoto Alhaji Muhammad Sa’ad Abubakar III ti kede wipe ola, ojo ketadinlogun osu karun ni awe Ramadan odun yi o bere. O se ikede yi leyin igba ti won ri osupa ni ilu Maiduguri, Damaturu, Gumel, Dutse, Minna, Sokoto ati awon ilu miran.

O ro awon musulumi ododo lati gbiyanju lati gba awe na, ki won si gbadura fun ifowosopo ati alafia orilede Nigeria.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply