Awon eyan merinla ti so emi won nu ninu ikolu to waye ni ipinle Plateau

0

Awon Fulani daran-daran ni ana ojo keji osu kesan se ikolu tuntun ni agbegbe Jos South ati ijoba ipinle Bassa ni ipinle Plateau. Awon eyan merinla lo so emi won nu ninu ikolu na.

Ikolu na waye leyin ose kan ti awon Fulani daran-daran pa ojise Olorun kan ati awon molebi re ni ijoba ipinle Barkin Ladi. Awon agbofinro ti wa bere iwadi to peye lori oro na, won si ti se eye ikeyin fun awon to so emi won nu.

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply