Awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam lo se ikolu si ibudo awon omo ologun ni ipinle Borno

0

Awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam ni ale ana lo se ikolu si awon omo egbe 33 Army Artillery ni ilu Maiduguri ni ipinle Borno. Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won se, won fi to wa leti wipe awon omo egbe agbesunmomi na lo yo kele-kele wo inu ibudo awon omoologun na ni nkan bi ago mesan ale pelu okada, ti won si yin ado oloro na.

Opolopo awon eyan lo so emi won nu ninu ikolu na, ti awon miran si farapa yana-yana. Iwadi to peye ti wa bere lori oro na, won si ti pinu lati mu awon ti won se agbateru isele na.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply