Awon olopa ipinle Eko ti fi Arakunrin ati Arabirin Bobrisky si atimole lo’ni. Jaaaaaaykub!

0

Gege bi atejade ati afihan awon eyan ti oro na se oju won, won so wipe arakunrin ati arabirin Bobrisky ti wa ni atimole awon olopa. Idi ti isele yi fi waye si je kayefi fun gbogbo eniyan sugbon won fi ye wa wipe won ti setan lati gbe arakunrin na lo si ilu Abuja ni aro kutu-kutu ola.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply