Eni to se atokun si riri owo ni ikoyi (Ikoyi Whistle-blower) ti gbera kuro ni orilede Nigeria leyin igba to gba N421 million.

0

Eni to se atokun bi ajo EFCC se ri owo toto N13bn ninu ile kan ni Ikoyi, ipinle Eko ti gba eto re (N421m). O si ti gbera kuro ni orilede Nigeria. Agbejoro fun arakunrin na Yakubu Galadima nigba ton ba awon akoroyin Punch soro so wipe ijoba apapo ti mu ileri won se pelu bi won se san owo na fun arakunrin na. O so siwaju si wipe won o san gbogbo owo na tan sugbon die ti de owo arakunrin na, beeni won ti fi lokan bale wipe lai pe awon yo san iyoku.

  Ni ipari, agbejoro Yakubu Galadima fi idi re mule wipe arakunrin na ti kuro ni orilede yi, ni kete to ri owo na gba, o si ro ijoba apapo ki won gbiyanju lati san owo na pe lai pe.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply