Gbajugbaja odomode olorin WizKid ati akegbe re Tiwa Savage ti se obe alata suwe-suwe

0

Ninu afihan agbejade mohun-maworan (fidio)kan ti odomode kunrin olorin WIZ KID sese gbejade to pe akole re ni FEVER ni akegbe re Tiwa Savage ti gbe laruge ti won si jo fi ife jan si ara won.

Ife laarin awon olorin mejeji yi po de bi wipe awon ololufe won ti bere sini fura siwon wipe won tin gbe nkan gba eyin adogan. Sugbon fidio na ta lenu yeri-yeri be obe alata suwe-suwe.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply