Ife bi eji owuro ni eleyi o! LOL

0

Arabirin kan se atejade kan lori ero ayelujara twitter wipe awon obi ohun se igbeyawo won leyin ojo meta pere ti won pade,won si ti wa papo fun odun metadinlogoji. Se iru nkan bayi si le sele laye ta wayi? Pelu awon slay mama! Hehehe!

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply