Ile ejo ti fagile esun ti awon alatako fi kan Senito Ademola Adeleke

0

Ile ejo agba to wa ni ilu Osogbo ni ipinle Osun ti fagile esun ti awon alatako Senito Ademola Adeleke fi kan latari wiwole re gege bi oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe egbe oloselu PDP.

Adajo agba Justice David Oladimeji leyin igba to ri aridaju wipe esun ti ogbeni Rasheed Olatunji ati Idowu Oluwaseun fi kan arakunrin na o lese nile. Adajo na so siwaju si wipe ko si enikeni abi nkan to le dena ogbeni Ademola Adeleke lona lati dibo fun ipo Gomina ipinle Osun ninu idibo ton bo lona.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply