Owo awon agbofinro ti te awon adigunjale meji ni opopona Lekki si Epe ni ipinle Eko.

0

 

Awon agbofinro RRS ton soku ekun ilu Eko ti mu awon ogbontarigi adigunjale meji ni opopona Epe si Lekki. Awon adigunjale na ti won ma n’se ise buruku won ni alale ati larin oru ni won gbamu ni nkan bi ago mewa ni ana.

Awon agbofinro na ti gbe won lo si ago olopa Base 129 ni ipinle Eko. Won si ti pinu lati gbe won lo, ki won si lo fi oju ba ile ejo ni ose ton wole bo yi.  Afi ki Olorun ma da abo re bo wa o. Amin.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply