Iro ni, Ki se Buhari lo soro. Ile ise iroyin Sahara lo so be.

0

Ile ise iroyin Sahara reporters ti tu asiri awon osise Buhari. Won so ninu atejade ti won se lori ero ayelujara twitter wipe, Ohun eni ti won fi ranse si awon ati si gbogbo omo Nigeria ki se ti Aare Buhari rara.

Oro yi ti wa fa ariyan-jiyan wipe boya iro ni abi ooto. Afi ki Olorun gba wa.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply