Kayefi nla lo je nigba ti ejo abami kan gbe millionu mẹ́rìndínlógójì (36million naira) mi ninu ile ise JAMB ni ilu Makurdi.

1

Iroyin fi to wa leti wipe ejo abami  kan gbe owo to to millionu mẹ́rìndínlógójì mi ninu ile ise JAMB to wa ni ilu Markurdi, ni ipinle Benue. Awa ke si gbogbo awon ode ati akinkanju eniyan lati jade sita lati ba wa pa ejo abami yi.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

1 COMMENT

Leave a Reply Cancel reply