6.6 C
London
Monday, February 17, 2020

Alai mo ore lasan-lasan ni ‘K1 De Ultimate’- Obesere lo so be

Gbajugbaja olorin Fuji ati ogbontarigi osere tiata Abass Akande Obesere ninu atejade kan to se lori oro ija to waye laarin Alhaji Wasiu Ayinde ati Gomina ipinle Eko Akinwumi Ambode so wipe alai mo...

Ogbeni Fela Durotoye ti gba iwe ase lati egbe oloselu ANN lati tesiwaju ninu...

Oludije fun ipo Aare, Ogbeni Fela Durotoye ti gba iwe ase lati egbe oloselu ANN lati tesiwaju ninu ipinu re lati dije fun ipo Aare ni odun 2019. Eyi ti fi ipinu Ogbeni Durotoye...

Aare Buhari ati awon agbagba ninu egbe oloselu APC peju sibi iwode itagbangba egbe...

Aare Buhari ati awon agbagba ninu egbe oloselu APC peju sibi iwode itagbangba fun eto idibo fun oludije fun ipo Gomina ipinle Osun Gboyega Oyetola ni ilu Osogbo. Idunu ati ayo ni Gomina ipinle na...

Owo ti ba oloselu agba ni ipinle Osun, Timothy Owoeye nibi to tin we...

Owo awon ara ilu ti ba oloselu agba ati asoju ijoba ipinle Ilesa West ni ile igbimo asofin ti ipinle Osun Hon, Timotjy Owoeye nibi to tin we ni iho-ho laarin oja ni ipinle...

Amir, omo Sultan ti ilu Sokoto ti farapa ninu ijamba oko

Isele ijamba oko kan to waye ni nkan bi ago mejila ni iroyin fi to wa leti wipe Amir, omo Sultan ilu Sokoto ti farapa yana-yana. Gege bi oro ti awon ti oro na se...

Awon agbebon kan ti ji ojise Olorun ijo Katoliki mimo kan gbe ni ipinle...

Ojise Olorun Christopher Ogaga ti ijo Katoliki mimo Emmanuel Catholic Church Oviri-Okpe ni ilu Okpe, ipinle Deltani iroyin fi to wa leti wipe awon agbebon kan ti ji gbe. Ojise Olorun na, eni to tun...

Temi, omobirin ogbontarigi onisowo Femi Otedola ti keko jade ni ile iwe giga University...

Ninu atejade ati afihan awon aworan ti gbajugbaja ati ogbontarigi onisowo Femi Otedola fi han lori ero ayelujara instagram, o fi han wipe omobirin re omidan Temi Otedola ti keko gboye ni ile iwe...

Awon eyan merinla ti so emi won nu ninu ikolu to waye ni ipinle...

Awon Fulani daran-daran ni ana ojo keji osu kesan se ikolu tuntun ni agbegbe Jos South ati ijoba ipinle Bassa ni ipinle Plateau. Awon eyan merinla lo so emi won nu ninu ikolu na. Ikolu...

Asoju Aare Yemi Osinbajo ti se atejade kan lati se atupale ati atunto ajo...

Asoju Aare Yemi Osinbajo loni ti se atejade kan lati se atunto patapata ajo Special Anti-Robbery Squad (SARS). Atunto na waye leyin opopopo igbe ati edun okan ti awon omo Nigeria n ke lojojumo...

Kosi iyato laarin Yemi Osinbajo ati Judasi – Femi Fani Kayode lo so be

Ogbeni Femi Fani Kayode ti fi ibanuje re han si oro ati atejade ti igbakeji Aare Yemi Osinbajo se nipa awon ojise Olorun nigba ton ba awon akeko soro nibi ipade 30th National Biennial...