9.3 C
London
Friday, September 25, 2020

Pa Adebayo Faleti, Onífìlà Gòbì – a Yoruba icon has gone to rest! by...

0
Not many people did as much, or fared as well as Baba Fálétí in making the Yoruba language; the culture, and its premier, unique idiosyncrasies star quality within the pantheon of other cultures. Nothing we...

Agba-oje osere ati akowe, Baba Adebayo Faleti ti ku. ...

1
Agba-oje ninu ere itage, gbajugbaja osere ati eni akoko to tunmo orin aroko orilede (National Anthem and Pledge) Nigeria lati ede Geesi si ede Yoruba ti ku. Baba Adebayo faleti eni to gba orisirisi...

O GA O!. Arabirin ojowu kan gba emi oko re nitori pe o fe...

2
Arabirin omo odunkandinlogoji (39yrs) kan ti oruko re n je Omotayo Salawudeen lo ti jewo fun awon agbofinro wipe ohun ni ohun gbe ise fun agbenipa lati gba emi oko re, ologbe Hakeem Salwudeen...

Arakunrin kan ji ara-re gbe, osi fe gba owo to to ogota millionu (60million)...

2
Awon olopa ipinle Eko ti mu arakunrin kan eni to paro wipe awon ajinigbe ti ji oun gbe lati gba owo lowo awon molebi re. Gege bi iroyin ti iwe iroyin Daily Post se, ogbeni...

Ogbontarigi Ajinigbe Evans ti bo lowo awon olopa.

0
Leyin gbogbo ariwo lori esun ti awon agbofinro fi kan ogbontarigi ajinigbe Chukwuduneme Onwuamadike ti gbogbo eyan mon si Evans, Iroyin fi to wa leti wipe odaran na ti bo mo awon olopa lowo. Gege...

Yoruba language comes to Viva Naija!

0
This is what we live for!!! Bringing the language to the people, to the youth, to Nigeria!! Just last week, we signed a contract with Kolly_Moore to give us weekly updates in Yoruba language....

Meji ninu awon omobirin chibok to salo mo awon agbesunmomi Bokoharam lowo, lo se...

1
Joy Bishara , omo ogunodun (20yrs), ati Lydia Pogu ,omo odun kokandinlogun (19yrs) meji ninu awon omobirin chibok to salo mo awon agbesunmomi Bokoharam lowo ni odun 2014 ni won lo se ipade pelu...

Iro ni, Ki se Buhari lo soro. Ile ise iroyin Sahara lo so be.

0
Ile ise iroyin Sahara reporters ti tu asiri awon osise Buhari. Won so ninu atejade ti won se lori ero ayelujara twitter wipe, Ohun eni ti won fi ranse si awon ati si gbogbo...

Ife bi eji owuro ni eleyi o! LOL

0
Arabirin kan se atejade kan lori ero ayelujara twitter wipe awon obi ohun se igbeyawo won leyin ojo meta pere ti won pade,won si ti wa papo fun odun metadinlogoji. Se iru nkan bayi...