9.3 C
London
Friday, September 25, 2020

Iya Gomina ipinle Bayelsa Arabirin Goldcoast Dickson ti ku

0
Ibanuje nla lo je nigbati iroyin iku Arabirin Goldcoast Dickson iya Gomina ipinle Bayelsa Seriake Dickson to wa leti. Ile iwosan University of Texas MD Anderson Cancer Centre, Houston, Texas, United States ni iya...

Ile ejo ti fagile esun ti awon alatako fi kan Senito Ademola Adeleke

0
Ile ejo agba to wa ni ilu Osogbo ni ipinle Osun ti fagile esun ti awon alatako Senito Ademola Adeleke fi kan latari wiwole re gege bi oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe...

Igbakeji Aare Yemi Osinbajo ti da oga agba ajo DSS Ogbeni Lawal Daura duro...

0
Latari idena ti awon osise ajo DSS se loni ni ile igbimo asofin, ti won si ko lati fun awon Senito laye lati wo inu ibise won, Igbakeji Aare Yemi Osinbajo se atejade kan...

Oludije fun ipo Aare; Arakunrin Fela Durotoye ati Ogbeni Omoyele Sowore latari akitiyan won...

1
Arakunrin Fela Durotoye ati ikan gboogi ninu awon akegbe re Ogbeni Omoyele Sowore ti pinu lati fowosowopo ninu akitiyan won lati du ipo Aare orilede Nigeria ni odun 2019. Eyi waye latari ife won...

Awon Senito Mẹdogun ti kuro ninu egbe oloselu APC bo si egbe oloselu PDP

0
Aare ile igbimo asofin orilede Nigeria Bukola Saraki loni nibi ipade awon omo egbe ti fi han wipe awon Senito Medogun ti pinu lati fi egbe oloselu APC sile, lasi ti darapo pelu egbe...

Gbajugbaja agbaboolu Mesut Ozil ti pinu lati feyinti nitori iwa eleyameya ati ai-lakasi

0
Gbajugbaja odomodekunrin agbaboolu Mesut Ozil ti pinu lati feyinti gege bi agbaboolu fun orilede JAMANI latari iwa eleyameya ati ailakasi ti Aare orilede JAMANI wu si leyin idije ifesewonse agbaye Fifa Worldcup to waye...

Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ti farahan gege bi omo oko nigba ti...

0
Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ni won ti fi je oye Waziri Ilorin, oye ti baba re Dr. Abubakar Olusola Saraki je ki olojo to de. Ayeye ifinijoye na waye ni Aafin Oba...

Orilede Faranse ti gba ife eye agbaye fun odun 2018 leyin igba ti won...

0
Orilede Faranse ti gba ifi eye agbaye fun odun 2018 leyin igba ti won na orilede Croatia ni omi ayo merin si meji (2-1) ninu idije ifesewonse to waye ni orilede Russia loni. Ifewonse na...

Ogbeni Kayode Fayemi dupe lowo awon ololufe ati alatileyin re leyin igba to gbegba...

0
Eto idibo Gomina ipinle Ekiti to waye ni ojo kerinla osu keje odun 2018 nibi ti ogbeni Kayode Fayemi ti gbegba olubori. Ogbeni Kayode Fayemi bakana lo dupe gidigidi lowo awon ololufe ati awon...

Awon agba oloselu lati orisirisi egbe ti korajopo lati koju egbe oloselu APC ninu...

0
Ipalemo ati akitiyan awon oloselu lati orisirisi egbe oloselu to wa ni orilede Nigeria, lati gba ipo Aare orilede lowo egbe oloselu APC ti bere. Eyi waye latari ipade to waye laarin awon agba-agba...