Awon agbofinro ipinle Eko ti mu baba-alawo ton soju egbe okunkun Badoo. ...

Awon omo ile ise olopa ati awon agbofinro ton soju ipinle Eko ti mu arakunrin kan ti oruko re nje Fatai Adebayo eni ti gbogbo eyan mo si Alese. Arakunrin na ni awon olopa...

Ekaabo si Odun tuntun, Odun 2018. Odun Isegun ati Ayo lati oke wa...

Adura mi fun gbogbo wa ni wipe Olorun a fun wa ni isegun ati aseyori ni ona gbogbo, gbogbo idawole wa yo si yori si rere. A o ni foju sokun eni kan-kan ni...

Yusuf omokunrin kan soso Aare Buhari farapa ninu isele ijamba okada ni ale ana.

Omokunrin kan soso ti Aare Buhari bi Yusuf farapa yanana ninu ijamba okada kan to waye lana ni ale ana ojo kerindinlogbon osu kejila odun yi. Iwadi fi ye wa wipe ile iwosan Cedacrest...

Ija dopin, ogun si tan laarin Davido ati Wizkid.

Ija olojo pipe laarin gbajugbaja odomode olorin Wizkid ati akegbe re Davido lana ti pari ni bi ipade orin ti Wizkid gbe kale to waye ni ile itura Eko Hotel ni ipinle Eko.  Iyalenu...

AKU ODUN KERESIMESI O. ODUN A YABO FUN GBOGBO WA.

Aku odun keresimesi o, adura wa ni wipe ki odun na san wa si owo, ko san wa si omo, ko si san wa si alafai, aiku baale oro ni oruko Jesu Kristi olugbala...

Egungun kan pada si orun nigba ti oko ayokele kan gba ni ipinle Akwa...

Awako kan ni oju opopona Nwaniba Road ni Use Offot, Uyo, ni ipinle Akwa Ibom gba ara orun kan ti o si gba emi re. Gege bi iwadi, awon ti oro na se oju...

Oni ni ayeye ojo ibi odun kárùndínlọ́gọ́rin (75years) ti Aare Buhari.

Aare orilede Nigeria Muhamodu Buhari ti loni ojo ketadinlogun osu kejila odun 2017 pe omo odun márùndínlọ́gọ́rin (75years). Adura wa ni wipe ki olorun fun baba na ni ogbon, imon ati oye lati le...

Eni to se atokun si riri owo ni ikoyi (Ikoyi Whistle-blower) ti gbera kuro...

Eni to se atokun bi ajo EFCC se ri owo toto N13bn ninu ile kan ni Ikoyi, ipinle Eko ti gba eto re (N421m). O si ti gbera kuro ni orilede Nigeria. Agbejoro fun...

O ma se o! Ikan ninu awon omobirin gbajugbaja olorin Fuji, KWAM1 ti ku.

Arabirin Wasilat Olaronke Marshall, omobirin omo odun merinlelogbon (34years), omo gbajugbaja olorin KWAM1 ti ku ni orilede Canada. Awon molebi ati ore arabirin na so wipe o ku leyin aisan ranpe kan. Adura wa ni...

Atejade oruko ati aworan awon to gba ami eye nibi ayeye The Future Awards...

Atejade oruko awon ti won fi ami eye da lola nibi ayeye The Future Awards 2017 to waye ni ile itura Federal Palace Hotel ni ipinle Eko. Atejade na ni yi; THE FUTURE AWARDS AFRICA PRIZE...

Stay Connected

38,246FansLike
28FollowersFollow
18,335FollowersFollow
3,557FollowersFollow
83SubscribersSubscribe