Awon osise ajo EFCC gba posi, igba ati opolopo ogun abenugongo lowo awon odomode...

Awon osise ajo Economic and Financial Crimes Commission, EFCC, ti ipinle eko ti mu awon odomode marundinlogun ti won lu jibiti lori ero ayelujara. Oruko awon odaran na ni Adeyemi Tiwatope, 20; Odeyemi Olawale,...

Awon meta lo ku, ti awon meje si farapa ninu ikolu ti awon omo...

Awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam lale ana lo se ikolu ni ilu Maiduguri nibi ti awon eyan meta ti so emi won nu, ti awon meje si farapa. Gege bi atejade ti awon ti...

Olopa kan yin ibon pa oga re nitori omoge ni ipinle Adamawa.

Olopa kan ti oruko re n je , Bala Adamu ni iroyin fi to wa leti wipe o yin ibon pa oga ati olopa akegbe re kan ti oruko re n je Timothy leyin...

BBNaija 2018; Laarin ojo meji ti idije Big Brother Naija bere, Nina ati...

Awon oludije meji yi Nina ati Miracle ni ero mohun-maworan gbe nibi ti won tin fi enu ko ara won lenu ninu baluwe. Ojo keji pere re o. Hmmmm  

Edakun, ema se fun awon olopa ni oti mu. Oga Olopa Edgal Imohimi...

Oga olopa Edgal Imohimi leyin akiyesi to se nipa iwa-kiwa ti awon agbofinro to ba mu oti amupara ma n wu, o so wipe lati oni lo, enikeni o gbodo fun olopa kankan ni...
Obasanjo

Aare orilede nigbakanri oloye Olusegun Obasanjo nse ayeye ikeko gboye Phd ni ile iwe...

Aare orilede nigbakanri oloye Olusegun Obasanjo nse ayeye ikeko gboye Phd ni ile iwe giga National Open University. Oloye na gba oye Phd ninu eko Christian Theology. Iwuri nla lo je fun awon oluko...

Ajo NYSC ti da eto agunbaniro duro ni ipinle Benue ati Taraba latari ikolu...

Ajo National Youth Service Corps Management ti kede wipe gbogbo awon agunbaniro ti won pin si ipinle Benue ati Taraba ni lati sinmi fun igba die. Ikede yi waye latari ikolu ati ipaniyan ton...

Alase ati oludari Facebook. Ogbeni Mark Zuckerberg ti ya sare pa owo toto Billionu...

Odomode kunrin, alase ati oludari Facebook, ogbeni Mark Zuckerberg ti ninu odun yi pa owo toto billonu merin dollar ninu odun tuntun 2018 ta sese mu yi. Gbohun mi, baba gbohun mi.

Egbe agbaboolu Arsenal ti fo’rijagbo leyin igba ti Egbe agbaboolu Nottingham Forest foju won...

Egbe agbaboolu Arsenal fidi remi lana ninu idije FA CUP to waye laarin akegbe won Nottingham Forest. Omi ayo merin si meji (4-2)ni awon egbe agbaboolu Arsenal je ti won si mu omi si....

Gomina Nasir El-Rufia lo ki ojise Olorun Tunde Bakare leyin igba to gbo wipe...

Gomina ipinle Kaduna Nasir El-Rufai loni lo se abewo si ojise Olorun Tunde Bakare ni ijo re to wa ni ipinle Eko Latter Rain Assembly ni oni, ojo keje osu kini. Abewo yi waye...

Stay Connected

38,232FansLike
28FollowersFollow
18,339FollowersFollow
3,552FollowersFollow
83SubscribersSubscribe