4.2 C
London,uk
Sunday, November 19, 2017

#2017MTVEMAs. Atejade gbogbo awon to pegede nibi ayeye na.

Ayeye MTV European Music Awards to waye ni ale oni, ojo aiku ojo kejila osu kokanla ni ilu london lo ri opolopo awon olorin agbaye, ti won si gbiyanju lati ye won si fun...
feminism

It is okay not to like feminism but do not pass ignorance of it...

It is okay if you don’t like feminism, you don’t have to call yourself a feminist. The truth is, very few people care. You won’t be doing anyone a favour or disfavour, whichever be...

Awon olopa ipinle Eko ti fi Arakunrin ati Arabirin Bobrisky si atimole lo’ni. ...

Gege bi atejade ati afihan awon eyan ti oro na se oju won, won so wipe arakunrin ati arabirin Bobrisky ti wa ni atimole awon olopa. Idi ti isele yi fi waye si je...

Oga olopa ni ipinle Ondo Aminu Mustapha ti ku ninu isele ijamba oko kan...

  Ijoba ipinle Ondo ti fi idi ijamba oko to se iku pa oga olopa ni ipinle na ogbeni Aminu Mustapha mule. Isele na waye ni opopona Ondo si Ore ni agbegbe Omifon ni ijoba...

O ma se o! ogbeni Jide Tinubu, akobi oga agba egbe oloselu APC...

  Ibanuje nla lo je fun oga agba egbe oloselu APC, Asiwaju Bola Tinubu nigba ti iroyin iku akobi re ni okunrin ogbeni Jide Tinubu to leti. Ologbe na lo so emi re nu ni...

Otunba Gani Adams ti se tan lati je oye Aare Ona Kakanfo elekarundinlogun ti...

Otunba Gani Adams ti setan lati je oye Aare Ona Kankanfo elekarundinlogun ti ile Yoruba ni ojo ketala osu kini odun 2018. Afihan yi waye ninu atejade ti ogbeni Femi Adepoju se ni ana...

Ijoba apapo ti pinu lati so ile Fela Anikulapo Kuti ni ipinle Ogun di...

Gege bi atejade ti ijoba apapo se ti Ogbeni Lai Mohamed si so pelu ajosepo Gomina ipinle Ogun, won se afihan wipe ile ti ologbe Fela Anikulapo Kuti gbe dagba ni ipinle Ogun ni...

FG, Ogun Immortalise Fela, Convert Family House to Museum to be named Heritage Museum

The Federal Government and Ogun State have initiated moves to immortalise the Afrobeat meastro, the late Fela Anikulapo Kuti by turning the family home in Abeokuta into a museum. It is to be named Heritage...
patriarchy

Cower in my presence o mortal woman: A sarcastic look at patriarchy

It's no big deal he had sex on the first date. She's the slut who dared get laid on the first date. She got pregnant? What a careless woman who tried to trap him, gosh!...

Olu (oba) ti Warri ti fi Ayirimi Emami je oye igbakeji adari awon Itsekiri.

Olu ti Warri, HRM Ogiame Ikenwoli ti fi Oloye Ayiri Emami je oye Ologbotsere (Prime Minister) ti ilu Warri. Oye yi lo je ki Ayiri Emami je enikeji tabi igbakeji si Oba ilu Warri....

Stay Connected

37,922FansLike
27FollowersFollow
14,911FollowersFollow
3,627FollowersFollow
79SubscribersSubscribe